Yoruba: Aare Fifa bale si ilu Eko




Ààrẹ́ FIFA Gianni Infantino ti balẹ̀ sí ìlú Eko fún ìdije àmì ẹ̀yẹ Aisha Buhari tó ń wáyé lọ́wọ́ ní ìpínlẹ̀ ọ̀hún.

Ara àwọn ojú tó wà nínú àwòrán yìí ni gómìnà Babajide Sanwo-Olu àti Olórí ilé ìgbìmọ̀ aṣojúṣòfin àpapọ̀ Femi Gbajabiamila.


Post a Comment

Previous Post Next Post